Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràAwon adura ti a ba ji lati oju orundhikr 2

Awon adura ti a ba ji lati oju orun — dhikr 2

أذكار الاستيقاظ من النوم · Hisn al-Muslim · 2 / 4

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

( لاَ إِلَهَ إِلاَّ اللَّهُ وَحْدَهُ لاَ شَريكَ لَهُ، لَهُ الْمُلْكُ وَلَهُ الْحَمْدُ، وَهُوَ عَلَى كُلِّ شَيْءٍ قَدِيرٌ، سُبْحَانَ اللَّهِ، وَالْحَمْدُ للَّهِ، وَلاَ إِلَهَ إِلاَّ اللَّهُ، وَاللَّهُ أَكبَرُ، وَلاَ حَوْلَ وَلاَ قُوَّةَ إِلاَّ بِاللَّهِ الْعَلِيِّ الْعَظِيمِ، رَبِّ اغْفرْ لِي ).

Ko si enikankan ti ijosin to si ayaafi Allah nikan, ko si orogun fun un, ti E ni ola nse, ti E eyin nse, oun ni alagbara lori gbogbo nkan, mimo fun Allaah, eyin ti Allaah ni, ko si si eniti ijosin tosi ayafi Allaah,atipe Allaah ni o tobi ju, atipe ko si ogbon ko si agbara ayafi pelu Allaah Oba ti o ga ju ti O si tobi, Olohun Oba mi se aforijin fun mi . (1) ............................ (1) eniti o ba so eleyi, ti o ba se adura won o jepe re fun un, ti o ba wa dide ti o si se aluwaala leyinna ti o wa kirun won o gba irun re, Al-Bukhaari pelu Al-Fat'hi, 3/39, pelu number 1154, ati eyiti o yato si i, atipe gbolohun re ti Ibnu Maajah ni, lo wo: Sahiihu Ibnu Maajah, 2/335

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè