Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràAwon adura ti a ba ji lati oju orundhikr 1

Awon adura ti a ba ji lati oju orun — dhikr 1

أذكار الاستيقاظ من النوم · Hisn al-Muslim · 1 / 4

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

( الْحَمْدُ للَّهِ الَّذِي أَحْيَانَا بَعْدَ مَا أَمَاتَنَا، وَإِلَيْهِ النُّشُورُ )

Eyin ti Olohun Oba ni, eniti o ji wa leyin igba ti O pa wa, odo Re si ni akojopo re yio pada si. (1) ........................ (1) Al-Bukhaari pelu Al-Fat'hi, 11/113

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè