( الْحَمْدُ لِلَّهِ الَّذِي عَافَانِي فِي جَسَدِي، وَرَدَّ عَلَيَّ رُوحِي، وَأَذِنَ لي بِذِكْرِهِ )
Gbogbo eyin ti Olohun Oba ni eniti o fun mi ni alaafia ni ara mi, ti O si da emi mi pada fun mi, ti O si yonda fun mi lati ranti Re. (1) ........................ (1) At-Tirmidhiy, 5/473. pelu number 3401, ki o si tun wo: Sohiihut Tirmidhiy, 144/3
Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham