Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràAwon adua leyin ti a ba salamo nibi irundhikr 7

Awon adua leyin ti a ba salamo nibi irun — dhikr 7

الأذكار بعد السلام من الصلاة · Hisn al-Muslim · 7 / 8

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

((لاَ إِلَهَ إِلاَّ اللَّهُ وَحْدَهُ لاَ شَرِيكَ لَهُ، لَهُ الْمُلْكُ وَلَهُ الْحَمْدُ يُحْيِي وَيُمِيتُ وَهُوَ عَلَى كُلِّ شَيْءٍ قَدِيرٌ)) عَشْرَ مَرّاتٍ بَعْدَ صَلاةِ الْمَغْرِبِ وَالصُّبْحِ.

(Kosi eniti ijosin to si ayafi Allaah ni Oun nikan koni orogun, tie ni ola atipe tie ni eyin O ma nda emi si osi ma n pa emi, atipe ohun ni olagbara lori gbogbo nkan) ao so o ni igba mewa)leyin irun magrib ati irun subhi (1) .................................. (1) Al-Tirmidhiy lo gba a wa, 5/515, pelu number 3474, ati Ahmad, 4/227, pelu number 17990, ki o si wo alaye agbejade re ninu tira: Zaadul Miaad 1/300.

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè