Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràAwon adua leyin ti a ba salamo nibi irundhikr 8

Awon adua leyin ti a ba salamo nibi irun — dhikr 8

الأذكار بعد السلام من الصلاة · Hisn al-Muslim · 8 / 8

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

((اللَّهُمَّ إِنِّي أَسْأَلُكَ عِلْماً نافِعاً، وَرِزْقاً طَيِّباً، وَعَمَلاً مُتَقَبَّلاً)) بَعْدَ السّلامِ مِنْ صَلاَةِ الفَجْرِ.

(Ire Oluwa dajudaju emi ntoro imo ti osanfani ni odo Re, ati arisiki ti o ma an, ati ise to je atewogba) ao maa sobe leyin igba ti a ba salamo leyin irun asunba (1) ................................ (1) Ibnu Maajah, pelu number 925, ati An-Nasaai ninu tira Amalul Yaomu wal Lailah, pelu number 102, ko si tun wo: Sohiihu Ibni Maajah, 1/152, ati Maj'mahuz Zawaaid 10/111, atipe yio si pada wa pelu number 95.

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè