Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràAdura ti a maa nse nigba ti a ba jeun tandhikr 2

Adura ti a maa nse nigba ti a ba jeun tan — dhikr 2

الدعاء عند الفراغ من الطعام · Hisn al-Muslim · 2 / 2

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

((الْحَمْدُ لِلَّهِ حَمْداً كَثِيراً طَيِّباً مُبَارَكاً فِيهِ، غَيْرَ [مَكْفِيٍّ وَلاَ ] مُوَدَّعٍ، وَلاَ مُسْتَغْنَىً عَنْهُ رَبَّنَا)).

Ope ni fun Olohun, o pe topo to daa to si ni ibukun ninu, ope ti n ko le du ti yoo fi dogba pelu oore ti Olohun se fun mi, ope ti ko se e pati ti ko si see ma se rara.

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè