Ojú ìwé àkọ́kọ́›Àdúrà›Adura ti a maa nse nigba ti a ba jeun tan›dhikr 1
Adura ti a maa nse nigba ti a ba jeun tan — dhikr 1
الدعاء عند الفراغ من الطعام · Hisn al-Muslim · 1 / 2
((الْحَمْدُ لِلَّهِ الَّذِي أَطْعَمَنِي هَذَا، وَرَزَقَنِيهِ، مِنْ غَيْرِ حَوْلٍ مِنِّي وَلاَ قُوَّةٍ)).
Ope ni fun Olohun ti o se wipe O fun mi ni ounje yii je ti O si pese re fun mi ti ko ki n se ete Kankan lati odo mi ati agbara
Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham