((اللَّهُمَّ أَعِذْهُ مِنْ عَذَابِ القَبْرِ)) وإن قال: ((اللَّهُمَّ اجْعَلْهُ فَرَطاً وَذُخْراً لِوَالِدَيْهِ، وَشَفِيعاً مُجَاباً، اللَّهُمَّ ثَقِّلْ بِهِ مَوَازِينَهُمَا، وَأَعْظِمْ بِهِ أُجورَهُمَا، وَأَلْحِقْهُ بِصَالِحِ الْمُؤْمِنِينَ، وَاجْعَلْهُ فِي كَفَالَةِ إِبْرَاهِيمَ، وَقِهِ بِرَحْمَتِكَ عَذَابَ الْجَحِيمِ، وَأَبْدِلْهُ دَاراً خَيْراً مِنْ دَارِهِ، وَأَهْلاً خَيْراً مِنْ أَهْلِهِ، اللَّهُمَّ اغْفِرْ لِأَسْلاَفِنَا، وَأَفْرَاطِنَا، وَمَنْ سَبَقَنَا بِالْإِيمَانِ)) إن قال ذلك فَحَسَنٌ.
Olohun so o kuro nibi iya saare Ti o ba si tun so pe: Olohun ba ni se e ni asiwaju nkan ifipamo rere fun awon obi re mejeeji, ati olusipe ti won o gba ipe re, Olohun ba ni fi je ki osuwon awon obi re o kun keke, je ki laada won o po daadaa, ba ni da a po pelu awon enirere ninu awon olugbagbo ododo, ba ni fi si abe itoju anabi Ibrahim, Olohun ba ni so o pelu ike Re kuro ninu iya ina Jaheem, Olohun ba ni jogun ile ti o dara ju ile ti o ti kuro lo fun un, ati araale ti o dara araale re lo, Olohun forijin awon asiwaju wa ti won ti lo ati awon omowere iru wa ti won ti lo ati awon ti won saaju wa pelu igbagbo. A le wi eleyii naa.
Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham