Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràAdura sise ti a ba fe bo oku lojudhikr 1

Adura sise ti a ba fe bo oku loju — dhikr 1

الدعاء عند إغماض الميت · Hisn al-Muslim · 1 / 1

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

((اللَّهُمَّ اغْفِرْ لِفُلاَنٍ (بِاسْمِهِ) وَارْفَعْ دَرَجَتَهُ فِي الْمَهْدِيِّينَ، وَاخْلُفْهُ فِي عَقِبِهِ فِي الْغَابِرِينَ، وَاغْفِرْ لَنَا وَلَهُ يَا رَبَّ الْعَالَمِينَ، وَافْسَحْ لَهُ فِي قَبْرِهِ، وَنَوِّرْ لَهُ فِيهِ)).

Olohun forijin lagbaja (a o daruko re) gbe ipo re ga laarin awon olumona, se arole fun un lori awon ti o seku ninu awon aromodomo re, fori jin wa ati oun naa, Iwo Olohun Oba agbanlaaye, ba ni fe saare re fun un, ki O si ba ni tan imole sinu saare re fun un.

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè