Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràAwon adua leyin ti a ba salamo nibi irundhikr 3

Awon adua leyin ti a ba salamo nibi irun — dhikr 3

الأذكار بعد السلام من الصلاة · Hisn al-Muslim · 3 / 8

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

((لَا إِلَهَ إِلاَّ اللَّهُ وَحْدَهُ لاَ شَرِيكَ لَهُ، لَهُ الْمُلْكُ، وَلَهُ الْحَمدُ، وَهُوَ عَلَى كُلِّ شَيْءٍ قَدِيرٌ. لاَ حَوْلَ وَلاَ قُوَّةَ إِلاَّ بِاللَّهِ، لاَ إِلَهَ إِلاَّ اللَّهُ، وَلاَ نَعْبُدُ إِلاَّ إِيَّاهُ, لَهُ النِّعْمَةُ وَلَهُ الْفَضْلُ وَلَهُ الثَّنَاءُ الْحَسَنُ، لَا إِلَهَ إِلاَّ اللَّهُ مُخْلِصِينَ لَهُ الدِّينَ وَلَوْ كَرِهَ الكَافِرُونَ)).

(Ko si eni ti ijosin tosi ayafi Allaah ni Oun nikan, ko si orogun fun un tie ni ola, ti E si ni eyin nse, Oun si ni alagbara lori gbogbo nkan, ko si ogbon ko si agbara ayafi pelu Allaah, ko si eniti ijosin tosi ayafi Allaah nikan atipe awa ko ni sin elomii yato si I. Ti E ni ike nse, ti E ni ola nse atipe ti E ni eyin to Rewa nse, ko si eniti ijosin to si ayafi Allaah ni eniti a nse afomo Re fun, atipe awon keferi o ba korira bee) (1) ........................... (1) Muslim, 1/415, pelu number 594.

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè