((اللَّهُمَّ لَكَ رَكَعْتُ، وَبِكَ آمَنْتُ، وَلَكَ أَسْلَمْتُ، خَشَعَ لَكَ سَمْعِي، وَبَصَرِي، وَمُخِّي، وَعَــــظْمِي، وَعَصَبِي، [وَمَا استَقَلَّتْ بِهِ قَدَمِي])).
(Ire Oluwa ni morukuhu fun IRe nimogbagbo atipe IRe ni moju wo juse fun. Igbonran mi lati tetisile fun ati iriran mi ati opolo mi ati egun mi ati iriran mi [ati ohun ti ese mi duro lelori]) (1) ........................... (1) Muslim, 1/534, pelu number 771, ati awon meerin ninu awon ti won se tira sunan ayaafi Ibnu Maajah: Abu Daaud,, pelu number 760, ati number 761, ati At-Tirmidhiy, pelu number 3421, ati An-Nasaai, pelu number 1049, atipe ohun ti o wa laarin orun mejeeji gbolohun Ibnu Khuzaimah ni, pelu nnumber 607, ati Ibnu Ibbaan, pelu number 1901.
Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham