Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràGbigbe Olohun tobi pelu oko kookan nibi lile okodhikr 1

Gbigbe Olohun tobi pelu oko kookan nibi lile oko — dhikr 1

التكبير عند رمي الجمار مع كل حصاة · Hisn al-Muslim · 1 / 1

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

((يُكَبِّرُ كُلَّمَا رَمَى بِحَصَاةٍ عِنْدَ الْجِمَارِ الثَّلاَثِ، ثُمَّ يَتَقَدَّمُ، ويَقِفُ يَدْعُو مُسْتَقْبِلَ الْقِبلَةِ، رَافِعاً يَدَيْهِ بَعْدَ الْجَمْرَةِ الْأُولَى وَالثَّانِيَةِ. أَمَّا جَمْرَةُ الْعَقَبَةِ فَيَرْمِيهَا وَيُكَبِّرُ عِنْدَ كُلِّ حَصَاةٍ وَيَنْصَرِفُ وَلاَ يَقِفُ عِنْدَهَا)).

Yio gbe Olohun tobi ni gbogbo igba ti o ba nju oko kookan ni awon aaye meteeta ti a ti ma nju oko, leyinna yio sun siwaju, yio o duro yio si se adua ni eniti o da oju ko qibla, leniti yio gbe owo re mejeeji soke nibi aaye iju oko alakoko ati eleekeji. Ama nibi aaye iju oko ti o gbeyin yio ju u, yio si gbe Olohun tobi nibi ojo kookan yio si maa lo ko si nii duro nibe.

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè