Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràAwon Adura Aro Ati Aledhikr 19

Awon Adura Aro Ati Ale — dhikr 19

أذكار الصباح والمساء · Hisn al-Muslim · 19 / 24

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

((لاَ إِلَهَ إِلاَّ اللَّهُ، وَحْدَهُ لاَ شَرِيكَ لَهُ، لَهُ الْمُلْكُ وَلَهُ الْحَمْدُ وَهُوَ عَلَى كُلِّ شَيْءٍ قَدِيرٌ)) (مائةَ مرَّةٍ إذا أصبحَ).

Ko si enikankan ti ijosin to si ni ododo ayafi Allah lOun nikan, kosi orugun fun Un, ti E ni ola ti E ni ope, Oun naa ni alagbara lori gbogbo nkan… Ao wi eleyi ti a ba ji nigba ogorun.

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè