Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràAdura ti a maa nse ki a to sundhikr 4

Adura ti a maa nse ki a to sun — dhikr 4

أذكار النوم · Hisn al-Muslim · 4 / 13

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

((بِاسْمِكَ رَبِّي وَضَعْتُ جَنْبِي، وَبِكَ أَرْفَعُهُ، فَإِن أَمْسَكْتَ نَفْسِي فارْحَمْهَا، وَإِنْ أَرْسَلْتَهَا فَاحْفَظْهَا، بِمَا تَحْفَظُ بِهِ عِبَادَكَ الصَّالِحِينَ)).

Pelu oruko Iwo Olohun Oba ِِِAseda mi, mo fi egbe mi le ile, pelu oruko Re naa ni ma fi gbe e dide pada, ti O ba gba emi mi, ba mi se ike re, ti O ba si da emi mi si, ba mi fi iso Re so o, pelu iso re ti o fi nso awon erusin Re rere

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè