Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràOhun ti won ma nso nibi ijokodhikr 1

Ohun ti won ma nso nibi ijoko — dhikr 1

ما يقال في اﻟﻤﺠلس · Hisn al-Muslim · 1 / 1

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

((عَنِ ابْنِ عُمَرَ رضي الله عنه قَاَلَ: كَانَ يُعَدُّ لِرَسُولِ اللَّهِ صلى الله عليه وسلم فِي الْمَجْلِسِ الوَاحِدِ مِائَةُ مَرَّةٍ مِنْ قَبْلِ أَنْ يَقُومَ: ((رَبِّ اغْفِرْ لِي، وَتُبْ عَلَيَّ، إِنَّكَ أَنْتَ التَّوَّابُ الغَفُورُ)).

Lati odo Ibnu Umar – ki Olohun yonu si awon mejeeji – o so pe: Won maa nka fun ojise Olohun – ki ike ati ola Olohun maa ba a – nibi ijoko kan ni igba ogorun siwaju ki o to dide: Ire Olohun se aforijin fun mi, ki O si gba tuuba mi, dajudaju Ire ni Oba ti maa ngba tuuba ti si maa nfi ori jinni.

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè