Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràAdura ti a maa nse ti afefe ba nfedhikr 2

Adura ti a maa nse ti afefe ba nfe — dhikr 2

دعاء الريح · Hisn al-Muslim · 2 / 2

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

((اللَّهُمَّ إِنِّي أَسْأَلُكَ خَيْرَهَا، وَخَيْرَ مَا فِيهَا، وَخَيْرَ مَا أُرْسِلَتْ بِهِ، وَأَعُوذُ بِكَ مِنْ شَرِّهَا، وَشَرِّ مَا فِيهَا، وَشَرِّ مَا أُرْسِلَتْ بِهِ)).

Olohun, Emi ntoro lowo Re oore afefe yii ati oore ti nbe ninu re ati oore ti won fi ran afefe naa, mo si n fi O wa iso kuro nibi aburu afefe yii, ati aburu to wa ninu afefe yii, ati aburu ti won ranse re wipe ki o lo se.

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè