Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràAdura ijoko laarin iforikanle mejidhikr 2

Adura ijoko laarin iforikanle meji — dhikr 2

دعاء الجلسة بين السجدتين · Hisn al-Muslim · 2 / 2

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

((اللَّهُمَّ اغْفِرْ لِي، وَارْحَمْنِي، وَاهْدِنِي، وَاجْبُرْنِي، وَعَافِنِي، وَارْزُقْنِي، وَارْفَعْنِي)).

(Ire Oluwa fi ori jinmi atipe ki o kemi atipe ki o fimi mona atipe kio bukun mi, ki o si fun mi ni alaafia, kio si fi arisiki fun mi kio si gbemiga) (1) ............................... (1) Awon ti won se tira Sunan ni won gbe e jade ayaafi An-Nisaai: Abu Daaud, 1/231, pelu number 850, ati At-Tirmidhiy, pelu number 284, ati 285, ati Ibnu Maajah, pelu number 898, ki o si tun wo: Sohiihut Tirmidhiy, 1/90, ati Sohiihu Ibni Maajah, 1/148.

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè