Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràOla tin be fun mima se afomo ati mima fi eyin fun Olohun ati mima se laa ilaha illal laah ati mima gbe Olohun tobidhikr 7

Ola tin be fun mima se afomo ati mima fi eyin fun Olohun ati mima se laa ilaha illal laah ati mima gbe Olohun tobi — dhikr 7

فضل التسبيح و التحميد، و التهليل، و التكبير · Hisn al-Muslim · 7 / 12

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

وَقَالَ صلى الله عليه وسلم: ((يَا عَبْدَ اللَّهِ بْنَ قَيْسٍ أَلاَ أَدُلُّكَ عَلَى كَنْزٍ مِنْ كُنُوزِ الْجَنَّةِ))؟ فَقُلْتُ: بَلَى يَا رَسُولَ اللَّهِ، قَالَ: ((قُلْ لاَ حَوْلَ وَلاَ قُوَّةَ إِلاَّ بِاللَّهِ)).

O tun so – ki ike ati ola Olohun maa ba a – pe: Ire Abdullaah omo Qois! O o wa je ki ntoka re si pepe oro kan ninu awon pepe oro aljannah? Mo si so pe: mo fe bee ire ojise Olohun, o so pe: so pe: : La aola wala quwwata illa billah

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè