Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràOhun ti eniti alamori ti o dun mo ninu tabi ti o korira ba de ba a maa sodhikr 1

Ohun ti eniti alamori ti o dun mo ninu tabi ti o korira ba de ba a maa so — dhikr 1

ما يقول من أتاه أمر يسره أو يكرهه · Hisn al-Muslim · 1 / 1

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

كَانَ النَّبِيُّ صلى الله عليه وسلم إِذَا أَتَاهُ الْأَمْرُ يَسُرُّهُ قَالَ: ((الْحَمْدُ لِلَّهِ الَّذِي بِنِعْمَتِهِ تَتِمُّ الصَّالِحَاتُ)) وَإِذَا أَتَاهُ الْأَمْرُ يَكْرَهُهُ قَالَ: ((الْحَمْدُ لِلَّهِ عَلَى كُلِّ حَالٍ)).

Anabi – ki ike ati ola Olohun maa ba a – je eniti o ma nso nigbati alamori ti o dun mo on ba de ba a pe: Ope ni fun Olohun Oba ti o se wipe pelu idera Re ni gbogbo daada fi maa npe. Ti alamori ti o korira ba si de ba a yio so pe: Ope ni fun Olohun Oba lori gbogbo isesi.

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè