Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràNinu Adura ti a maa nse nigba ti ojo ba ti pojudhikr 1

Ninu Adura ti a maa nse nigba ti ojo ba ti poju — dhikr 1

من أدعية الاستصحاء · Hisn al-Muslim · 1 / 1

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

((اللَّهُمَّ حَوَالَيْنَا وَلاَ عَلَيْنَا، اللَّهُمَّ عَلَى الآكَامِ وَالظِّرَابِ، وَبُطُونِ الْأَوْدِيَةِ، وَمَنَابِتِ الشَّجَرِ)).

Iwo Olohun, awon ayika wa ni ki o maa ro o si ma se ro o le wa lori, je ki o maa ro sori awon ile giga ati awon oke keekeekee, ati si inu awon afonufoji ati sara awon itakun igi.

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè