Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràAdura ti a maa nse ti a ba lo se ibewo awon saaredhikr 1

Adura ti a maa nse ti a ba lo se ibewo awon saare — dhikr 1

دعاء زيارة القبور · Hisn al-Muslim · 1 / 1

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

((السَّلاَمُ عَلَيْكُمْ أَهْلَ الدِّيَارِ، مِنَ الْمُؤْمِنِينَ وَالْمُسْلِمِينَ، وَإِنَّا إِنْ شَاءَ اللَّهُ بِكُمْ لاَحِقُونَ، [وَيَرْحَمُ اللَّهُ الْمُسْتَقدِمِينَ مِنَّا وَالْمُسْتأْخِرِينَ] أَسْاَلُ اللَّهَ لَنَا وَلَكُمُ الْعَافِيَةَ)).

Alaafia Olohun ki o maa ba eyin olugbe ibi ninu mumini ati musulumi, bi Olohun ba fe awa naa fee ba yin nibi, Olohun yio ba ni ke awon olugbawaju inu wa ati awon ti won nbo leyin, A be Olohun fun awa ati eyin naa ini amojukuro Olohun

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè