Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràOhun ti a maa n fi wa isora fun omo ti a ba bidhikr 1

Ohun ti a maa n fi wa isora fun omo ti a ba bi — dhikr 1

ما يعوذ به الأولاد · Hisn al-Muslim · 1 / 1

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

كَانَ رَسُولُ اللَّهِ صلى الله عليه وسلم يُعَوِّذُ الحَسَنَ وَالحُسَينَ رضي الله عنهما ((أُعِيذُكُمَا بِكَلِمَاتِ اللَّهِ التَّامَّةِ مِنْ كُلِّ شَيْطَانٍ وَهَامَّةٍ، وَمِنْ كُلِّ عَيْنٍ لاَمَّةٍ)).

Ojise Olohun maa nwa isora fun Hassan ati Hussein, ki Olohun bani yonu si awon mejeeji pelu ko so bayii wipe: Mo nfi awon gbolohun Olohun Oba ti Ope wa isora fun eyin mejeeji kuro ni odo shaytan (esu) ati eranko tabi kokoro oloro, ati kuro nibi gbogbo oju-koju.

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè