يَقُولُ: ((اللَّهُمَّ رَبَّ هَذِهِ الدَّعْوَةِ التَّامَّةِ، وَالصَّلاَةِ الْقَائِمَةِ، آتِ مُحَمَّداً الْوَسِيلَةَ وَالْفَضِيلَةَ، وَابْعَثْهُ مَقَامَاً مَحمُوداً الَّذِي وَعَدْتَهُ، [إِنَّكَ لَا تُخْلِفُ الْمِيعَادَ])).
(Ire Oluwa Oba ti oni ipepe ti o pe yi ati irun ti won gbe duro yi fun anabi wa Muhammad ni aga wasila ati ola, atipe gbe e dide ni aye eleyin eyiti O ti se adehun re fun un, dajudaju Ire ki ye adehun) (1) ........................... (1) Al-Bukhaariy, 1/152, pelu number 614, gbolohun ti nbe ninu orun mejeeji yen ti Al-Bai'aqiy, 1/410. ti Alufa agba Abdul Azeez omo Baaz so pe o daa - ki Olohun ke e - ninu tira Tuhfatul Akh'yaar, oju ewe 38.
Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham