Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràAdura ti a ba fe jade kuro ninu iledhikr 2

Adura ti a ba fe jade kuro ninu ile — dhikr 2

الذكر عند الخروج من المنزل · Hisn al-Muslim · 2 / 2

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

(اللَّهُمَّ إِنِّي أَعُوذُ بِكَ أَنْ أَضِلَّ، أَوْ أُضَلَّ، أَوْ أَزِلَّ، أَوْ أُزَلَّ، أَوْ أَظْلِمَ، أَوْ أُظْلَمَ، أَوْ أَجْهَلَ، أَوْ يُجْهَلَ عَلَيَّ).

Ire Olohun Oba dajudaju emi sa di O nibi ki nsonu tabi ki won somi nu, tabi ki nye ese gere tabi ki won yemi lese gere, tabi kin se abosi eniyan tabi ki won se abosi simi, tabi ki nwu iwa aimokan tabi ki won wu iwa aimokan simi. (1) ............................................. (1) Awon ti won ni tira Sunnah: Abu Daaud, pelu number 5094, ati At-Tirmidhiy, pelu number 5501, ati An-Nasaaiy, pelu number 5501, ati Ibnu Maajah, pelu number 3884, ki o si tun wo: Sohiihut Tirnidhiy, 3/152, ati Sohiihu Ibnu Maajah, 2/336.

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè