Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràImaa se bi leri awon otadhikr 1

Imaa se bi leri awon ota — dhikr 1

الدعاء على العدو · Hisn al-Muslim · 1 / 1

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

((اللَّهُمَّ مُنْزِلَ الْكِتَابِ، سَرِيعَ الْحِسَابِ، اهْزِمِ الأَحْزَابَ، اللَّهُمَّ اهزِمْهُمْ وَزَلْزِلْهُمْ)).

Olohun Oba ti O so Al'qurani kale Oba Oluse isiro kiakia, ba mi bori awon ijo yii, Olohun bami bori won, ba mi mi won titi

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè