Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràAdura ibanuje abi ti oriri okan ba sele sinidhikr 1

Adura ibanuje abi ti oriri okan ba sele sini — dhikr 1

دعاء الهم والحزن · Hisn al-Muslim · 1 / 2

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

((اللَّهُمَّ إِنِّي عَبْدُكَ، ابْنُ عَبْدِكَ، ابْنُ أَمَتِكَ، نَاصِيَتِي بِيَدِكَ، مَاضٍ فِيَّ حُكْمُكَ، عَدْلٌ فِيَّ قَضَاؤُكَ، أَسْأَلُكَ بِكُــــلِّ اسْمٍ هُوَ لَكَ، سَمَّيْتَ بِهِ نَفْسَكَ، أَوْ أَنْزَلْتَهُ فِي كِتَابِكَ، أَوْ عَلَّمْتَهُ أَحَداً مِنْ خَلْقِكَ، أَوِ اسْتَأْثَرْتَ بِهِ فِي عِلْمِ الغَيْبِ عِنْدَكَ، أَنْ تَجْعَلَ القُرْآنَ رَبِيعَ قَلْبِي، وَنُورَ صَدْرِي، وَجَلاَءَ حُزْنِي، وَذَهَابَ هَمِّي)).

Olohun dajudaju emi ni eru Re, omo erukunrin Re, ati omo erubinrin Re, aaso ori mi nbe lowo Re, idajo Re yoo se lemi lori, ipebubu Re naa ba mi lara mu, mo fi gbogbo oruko Re be O, awon oruko ti O pe ara Re, abi ti O so o kale sinu tira Re, abi ti O fi mo enikan ninu awon eda Re, abi ti O fi pamo sinu imo koko lodo Re, ki O se Al'quraani ni ohun ti yio se iregbede okan mi, ati imole aya mi, ati ohun ti yio si ibanuje mi danu, ati ohun ti yio mu edun okan mi lo

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè