Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràBawo ni anabi – ki ike ati ola Olohun maa ba a – se ma nse afoma?dhikr 1

Bawo ni anabi – ki ike ati ola Olohun maa ba a – se ma nse afoma? — dhikr 1

كيف كان النبي يسبح؟ · Hisn al-Muslim · 1 / 1

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

عَنْ عَبْدِ اللَّهِ بْنِ عَمْرٍو رضي الله عنه قَالَ: ((رَأَيْتُ النَّبيَّ صلى الله عليه وسلم يَعْقِدُ التَّسْبِيحَ)) وفي زيادةٍ: ((بِيَمِينِهِ)).

Egbawa yi wa lati odo Abdullaah omo Abbaas – ki Olohun yonu si awon mejeeji – o so pe: Mo ri anabi – ki ike ati ola Olohun maa ba a – ti nse afomo pelu owo re. Ninu afikun kan: pelu owo otun re.

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè