Ojú ìwé àkọ́kọ́ÀdúràBawo ni a se ma nda keferi loun nigbati o ba salamodhikr 1

Bawo ni a se ma nda keferi loun nigbati o ba salamo — dhikr 1

كيف يرد السلام على الكافر إذا سلم · Hisn al-Muslim · 1 / 1

Kà · Gbọ́Fáìlì PDF

((إذَا سَلَّمَ عَلَيْكُمْ أَهْلُ الْكِتَابِ فَقُولُوا: وَعَلَيْكُمْ)).

Ti awon ti a fun ni tira ba salaamo siyin ki e fun won lesi pe: WA ALAIKUM ati eyin naa.

Gbọ́ · Ohùn Hamad al-Duraiham

Àdúrà · 15 èdè